2 “Ẹ sọ ọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kéde rẹ̀.
Ẹ gbé àmì kan dúró, ẹ sì kéde rẹ̀.
Ẹ má fi nǹkan kan pa mọ́!
Ẹ sọ pé, ‘Wọ́n ti gba Bábílónì.+
Ìtìjú ti bá Bélì.+
Méródákì wà nínú ìbẹ̀rù.
Ìtìjú ti bá àwọn ère rẹ̀.
Àwọn òrìṣà ẹ̀gbin rẹ̀ wà nínú ìbẹ̀rù.’