Diutarónómì 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o máa bẹ̀rù,+ òun ni kí o máa sìn,+ orúkọ rẹ̀ sì ni kí o máa fi búra.+ Róòmù 14:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “‘Bí mo ti wà láàyè,’+ ni Jèhófà* wí, ‘gbogbo eékún máa tẹ̀ ba fún mi, gbogbo ahọ́n máa jẹ́wọ́ ní gbangba pé èmi ni Ọlọ́run.’”+
11 Nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “‘Bí mo ti wà láàyè,’+ ni Jèhófà* wí, ‘gbogbo eékún máa tẹ̀ ba fún mi, gbogbo ahọ́n máa jẹ́wọ́ ní gbangba pé èmi ni Ọlọ́run.’”+