1 Sámúẹ́lì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí àwọn ará Áṣídódì dìde ní kùtùkùtù ọjọ́ kejì, Dágónì ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà.+ Torí náà, wọ́n gbé Dágónì, wọ́n sì dá a pa dà sí àyè rẹ̀.+
3 Nígbà tí àwọn ará Áṣídódì dìde ní kùtùkùtù ọjọ́ kejì, Dágónì ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà.+ Torí náà, wọ́n gbé Dágónì, wọ́n sì dá a pa dà sí àyè rẹ̀.+