Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Àìsáyà 51:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Òdodo mi sún mọ́lé.+ Ìgbàlà mi máa jáde lọ,+Apá mi sì máa dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́.+ Àwọn erékùṣù máa nírètí nínú mi,+Wọ́n sì máa dúró de apá* mi. Àìsáyà 62:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
5 Òdodo mi sún mọ́lé.+ Ìgbàlà mi máa jáde lọ,+Apá mi sì máa dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́.+ Àwọn erékùṣù máa nírètí nínú mi,+Wọ́n sì máa dúró de apá* mi.
11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+