Àìsáyà 29:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí Jèhófà ti da ẹ̀mí oorun àsùnwọra lù yín;+Ó ti pa ojú yín dé, ẹ̀yin wòlíì,+Ó sì ti bo orí yín, ẹ̀yin aríran.+
10 Torí Jèhófà ti da ẹ̀mí oorun àsùnwọra lù yín;+Ó ti pa ojú yín dé, ẹ̀yin wòlíì,+Ó sì ti bo orí yín, ẹ̀yin aríran.+