Àìsáyà 60:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+ Àìsáyà 60:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 O sì máa mu wàrà àwọn orílẹ̀-èdè,+O máa mu ọmú àwọn ọba;+Wàá sì mọ̀ dájú pé èmi Jèhófà ni Olùgbàlà rẹ,Alágbára Jékọ́bù sì ni Olùtúnrà rẹ.+
10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+
16 O sì máa mu wàrà àwọn orílẹ̀-èdè,+O máa mu ọmú àwọn ọba;+Wàá sì mọ̀ dájú pé èmi Jèhófà ni Olùgbàlà rẹ,Alágbára Jékọ́bù sì ni Olùtúnrà rẹ.+