Ìdárò 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ojú mi ti di bàìbàì nítorí omijé.+ Inú* mi ń dà rú. A ti tú ẹ̀dọ̀ mi jáde sí ilẹ̀, nítorí ìṣubú ọmọbìnrin* àwọn èèyàn mi,+Nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ jòjòló ń dá kú ní àwọn ojúde ìlú.+
11 Ojú mi ti di bàìbàì nítorí omijé.+ Inú* mi ń dà rú. A ti tú ẹ̀dọ̀ mi jáde sí ilẹ̀, nítorí ìṣubú ọmọbìnrin* àwọn èèyàn mi,+Nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ jòjòló ń dá kú ní àwọn ojúde ìlú.+