Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Àìsáyà 61:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+ Fílípì 2:5-7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+ 7 Ó tì o, àmọ́ ó fi gbogbo ohun tó ní sílẹ̀, ó gbé ìrísí ẹrú wọ̀,+ ó sì di èèyàn.*+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+ Fílípì 2:5-7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+ 7 Ó tì o, àmọ́ ó fi gbogbo ohun tó ní sílẹ̀, ó gbé ìrísí ẹrú wọ̀,+ ó sì di èèyàn.*+
5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+ 7 Ó tì o, àmọ́ ó fi gbogbo ohun tó ní sílẹ̀, ó gbé ìrísí ẹrú wọ̀,+ ó sì di èèyàn.*+