Àìsáyà 44:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+ Àìsáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+
23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+
13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+