Sekaráyà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà yóò sì jẹ́ Ọba lórí gbogbo ayé.+ Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan ní ọjọ́ yẹn,+ orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan.+ Róòmù 3:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àbí ṣé Ọlọ́run àwọn Júù nìkan ni?+ Ṣé kì í ṣe Ọlọ́run àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú?+ Bẹ́ẹ̀ ni, òun náà ni Ọlọ́run àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+
9 Jèhófà yóò sì jẹ́ Ọba lórí gbogbo ayé.+ Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan ní ọjọ́ yẹn,+ orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan.+
29 Àbí ṣé Ọlọ́run àwọn Júù nìkan ni?+ Ṣé kì í ṣe Ọlọ́run àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú?+ Bẹ́ẹ̀ ni, òun náà ni Ọlọ́run àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+