Àìsáyà 49:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó sọ fún mi pé: “Ìránṣẹ́ mi ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì,+Ẹni tí màá tipasẹ̀ rẹ̀ fi ẹwà mi hàn.”+ Àìsáyà 60:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn erékùṣù máa gbẹ́kẹ̀ lé mi,+Àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì ló ṣíwájú,*Láti kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,+Pẹ̀lú fàdákà wọn àti wúrà wọn,Síbi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ àti sọ́dọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí ó máa ṣe ọ́ lógo.*+
9 Torí àwọn erékùṣù máa gbẹ́kẹ̀ lé mi,+Àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì ló ṣíwájú,*Láti kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,+Pẹ̀lú fàdákà wọn àti wúrà wọn,Síbi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ àti sọ́dọ̀ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí ó máa ṣe ọ́ lógo.*+