Ìsíkíẹ́lì 33:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Àmọ́ tí olùṣọ́ náà bá rí i pé idà ń bọ̀, tí kò fun ìwo,+ tí àwọn èèyàn kò sì rí ìkìlọ̀ gbà, tí idà sì dé, tó sì gba ẹ̀mí* ẹnì kan nínú wọn, ẹni yẹn á kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, àmọ́ màá béèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ olùṣọ́ náà.’*+
6 “‘Àmọ́ tí olùṣọ́ náà bá rí i pé idà ń bọ̀, tí kò fun ìwo,+ tí àwọn èèyàn kò sì rí ìkìlọ̀ gbà, tí idà sì dé, tó sì gba ẹ̀mí* ẹnì kan nínú wọn, ẹni yẹn á kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, àmọ́ màá béèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ olùṣọ́ náà.’*+