Àwọn Onídàájọ́ 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ lọ bá àwọn ọlọ́run tí ẹ yàn, kí ẹ sì ké pè wọ́n pé kí wọ́n ràn yín lọ́wọ́.+ Kí wọ́n gbà yín sílẹ̀ nígbà tí wàhálà dé bá yín.”+ Àìsáyà 42:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 A máa dá wọn pa dà, ojú sì máa tì wọ́n gidigidi,Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ère gbígbẹ́,Àwọn tó ń sọ fún àwọn ère onírin* pé: “Ẹ̀yin ni ọlọ́run wa.”+
14 Ẹ lọ bá àwọn ọlọ́run tí ẹ yàn, kí ẹ sì ké pè wọ́n pé kí wọ́n ràn yín lọ́wọ́.+ Kí wọ́n gbà yín sílẹ̀ nígbà tí wàhálà dé bá yín.”+
17 A máa dá wọn pa dà, ojú sì máa tì wọ́n gidigidi,Àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé ère gbígbẹ́,Àwọn tó ń sọ fún àwọn ère onírin* pé: “Ẹ̀yin ni ọlọ́run wa.”+