Róòmù 3:15-17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.”+ 16 “Ìparun àti ìyà wà ní àwọn ọ̀nà wọn, 17 wọn kò sì mọ ọ̀nà àlàáfíà.”+
15 “Ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.”+ 16 “Ìparun àti ìyà wà ní àwọn ọ̀nà wọn, 17 wọn kò sì mọ ọ̀nà àlàáfíà.”+