Àìsáyà 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí Jèhófà ní ọjọ́ ẹ̀san,+Ọdún ẹ̀san torí ẹjọ́ lórí Síónì.+