-
Àìsáyà 23:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ní òpin àádọ́rin (70) ọdún, Jèhófà máa rántí Tírè, ó máa pa dà sídìí ọrọ̀ rẹ̀, á sì máa bá gbogbo ìjọba ayé tó wà lórí ilẹ̀ ayé ṣe ìṣekúṣe. 18 Àmọ́ èrè rẹ̀ àti ọrọ̀ rẹ̀ máa di ohun mímọ́ fún Jèhófà. Kò ní kó o pa mọ́ tàbí kó tò ó jọ, torí pé ọrọ̀ rẹ̀ máa di ti àwọn tó ń gbé iwájú Jèhófà, kí wọ́n lè jẹun ní àjẹyó, kí wọ́n sì wọ aṣọ aláràbarà.+
-