Àìsáyà 63:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí ìwọ ni Bàbá wa;+Bí Ábúráhámù ò tiẹ̀ mọ̀ wá,Tí Ísírẹ́lì ò sì dá wa mọ̀,Ìwọ Jèhófà, ni Bàbá wa. Olùtúnrà wa látìgbà àtijọ́ ni orúkọ rẹ.+
16 Torí ìwọ ni Bàbá wa;+Bí Ábúráhámù ò tiẹ̀ mọ̀ wá,Tí Ísírẹ́lì ò sì dá wa mọ̀,Ìwọ Jèhófà, ni Bàbá wa. Olùtúnrà wa látìgbà àtijọ́ ni orúkọ rẹ.+