Sáàmù 74:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+ 11 Kí ló dé tí o fi fa ọwọ́ rẹ sẹ́yìn, ọwọ́ ọ̀tún rẹ?+ Nà án jáde láti àyà rẹ,* kí o sì pa wọ́n run. Sekaráyà 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, áńgẹ́lì Jèhófà sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó kí o tó ṣàánú Jerúsálẹ́mù àti àwọn ìlú Júdà+ tí o ti bínú sí fún àádọ́rin (70) ọdún báyìí?”+
10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+ 11 Kí ló dé tí o fi fa ọwọ́ rẹ sẹ́yìn, ọwọ́ ọ̀tún rẹ?+ Nà án jáde láti àyà rẹ,* kí o sì pa wọ́n run.
12 Torí náà, áńgẹ́lì Jèhófà sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó kí o tó ṣàánú Jerúsálẹ́mù àti àwọn ìlú Júdà+ tí o ti bínú sí fún àádọ́rin (70) ọdún báyìí?”+