Sáàmù 92:12-14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ olódodo máa gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹWọ́n á sì tóbi bí igi kédárì ní Lẹ́bánónì.+ 13 Ilé Jèhófà ni a gbìn wọ́n sí;Wọ́n ń gbilẹ̀ ní àwọn àgbàlá Ọlọ́run wa.+ 14 Kódà nígbà arúgbó* wọn, wọ́n á máa lókun;+Wọ́n á ṣì máa ta kébé,* ara wọn á sì máa dán,+
12 Àmọ́ olódodo máa gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹWọ́n á sì tóbi bí igi kédárì ní Lẹ́bánónì.+ 13 Ilé Jèhófà ni a gbìn wọ́n sí;Wọ́n ń gbilẹ̀ ní àwọn àgbàlá Ọlọ́run wa.+ 14 Kódà nígbà arúgbó* wọn, wọ́n á máa lókun;+Wọ́n á ṣì máa ta kébé,* ara wọn á sì máa dán,+