Àìsáyà 44:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+ Àìsáyà 65:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Torí náà, ẹ yọ̀, kí inú yín sì máa dùn títí láé torí ohun tí mò ń dá. Torí wò ó! Mò ń dá Jerúsálẹ́mù láti mú ayọ̀ wáÀti àwọn èèyàn rẹ̀ láti jẹ́ orísun ìdùnnú.+ 19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+
28 Ẹni tó ń sọ nípa Kírúsì+ pé, ‘Òun ni olùṣọ́ àgùntàn mi,Ó sì máa ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́ délẹ̀délẹ̀’;+Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa tún un kọ́’Àti nípa tẹ́ńpìlì pé, ‘Wọ́n máa fi ìpìlẹ̀ rẹ lélẹ̀.’”+
18 Torí náà, ẹ yọ̀, kí inú yín sì máa dùn títí láé torí ohun tí mò ń dá. Torí wò ó! Mò ń dá Jerúsálẹ́mù láti mú ayọ̀ wáÀti àwọn èèyàn rẹ̀ láti jẹ́ orísun ìdùnnú.+ 19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+