11 “Torí láti yíyọ oòrùn dé wíwọ̀ rẹ̀, wọn yóò gbé orúkọ mi ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.+ Níbi gbogbo, wọ́n á mú kí ẹbọ rú èéfín, wọ́n á sì mú àwọn ọrẹ wá torí orúkọ mi, bí ẹ̀bùn tó mọ́; torí wọn yóò gbé orúkọ mi ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.