Jeremáyà 49:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,‘Tí màá mú kí a gbọ́ ìró ogun* ní Rábà+ àwọn ọmọ Ámónì.+ Ó máa di àwókù,Wọ́n á sì dáná sun àwọn àrọko* rẹ̀.’ ‘Ísírẹ́lì á sì sọ àwọn tó gba tọwọ́ rẹ̀ di ohun ìní,’+ ni Jèhófà wí.
2 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,‘Tí màá mú kí a gbọ́ ìró ogun* ní Rábà+ àwọn ọmọ Ámónì.+ Ó máa di àwókù,Wọ́n á sì dáná sun àwọn àrọko* rẹ̀.’ ‘Ísírẹ́lì á sì sọ àwọn tó gba tọwọ́ rẹ̀ di ohun ìní,’+ ni Jèhófà wí.