-
Ẹ́kísódù 9:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Yìnyín náà bọ́ lu gbogbo ohun tó wà nínú oko ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, látorí èèyàn dórí ẹranko, ó run gbogbo ewéko, ó sì run gbogbo igi oko.+
-
-
Ẹ́kísódù 9:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ọ̀gbọ̀ àti ọkà bálì ti run, torí pé ọkà bálì wà nínú ṣírí, ọ̀gbọ̀ sì ti yọ òdòdó.
-