Sáàmù 137:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 137 Létí àwọn odò Bábílónì,+ ibẹ̀ la jókòó sí. A sunkún nígbà tí a rántí Síónì.+ Àìsáyà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+ Àìsáyà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo ayé ti wá sinmi, ó bọ́ lọ́wọ́ ìyọlẹ́nu. Àwọn èèyàn ń kígbe ayọ̀.+ Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+
4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+
10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+