-
Àìsáyà 5:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Wọ́n ní háàpù àti ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín,
Ìlù tanboríìnì, fèrè àti wáìnì sì wà níbi àsè wọn;
Àmọ́ wọn ò ronú nípa iṣẹ́ Jèhófà,
Wọn ò sì rí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.
-
-
Àìsáyà 56:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Bí òní ṣe rí ni ọ̀la máa rí, ó tiẹ̀ máa dáa gan-an jù ú lọ!”
-
-
Émọ́sì 6:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Wọ́n ń dùbúlẹ̀ sórí àwọn ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe,+ wọ́n sì ń nà gbalaja sórí àga tìmùtìmù,+
Wọ́n ń jẹ àwọn àgbò inú agbo ẹran àti àwọn ọmọ màlúù* tí wọ́n bọ́ sanra;+
-