Àìsáyà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+ Ìsíkíẹ́lì 26:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá sọ ọ́ di àpáta lásán tó ń dán àti ibi tí wọ́n ti ń sá àwọ̀n.+ Wọn ò ní tún ọ kọ́ láé, torí èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. Ìsíkíẹ́lì 26:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wọ́n á kọ orin arò*+ torí rẹ, wọ́n á sì sọ fún ọ pé: “Wo bí o ti ṣègbé,+ ìwọ tí àwọn tó wá láti òkun ń gbé inú rẹ̀, ìwọ ìlú tí wọ́n ń yìn;Ìwọ àti àwọn* tó ń gbé inú rẹ jẹ́ alágbára lórí òkun,+Ẹ sì ń dẹ́rù ba gbogbo àwọn tó ń gbé ayé!
23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+
14 Màá sọ ọ́ di àpáta lásán tó ń dán àti ibi tí wọ́n ti ń sá àwọ̀n.+ Wọn ò ní tún ọ kọ́ láé, torí èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
17 Wọ́n á kọ orin arò*+ torí rẹ, wọ́n á sì sọ fún ọ pé: “Wo bí o ti ṣègbé,+ ìwọ tí àwọn tó wá láti òkun ń gbé inú rẹ̀, ìwọ ìlú tí wọ́n ń yìn;Ìwọ àti àwọn* tó ń gbé inú rẹ jẹ́ alágbára lórí òkun,+Ẹ sì ń dẹ́rù ba gbogbo àwọn tó ń gbé ayé!