Sáàmù 40:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+ Sáàmù 98:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+ Sáàmù 107:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí àwọn èèyàn máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà+ nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀Àti nítorí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀ lórí àwọn ọmọ èèyàn.+ Sáàmù 145:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 145 Màá gbé ọ ga, ìwọ Ọlọ́run mi Ọba,+Màá yin orúkọ rẹ títí láé àti láéláé.+ Sáàmù 145:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìran dé ìran yóò máa yin àwọn iṣẹ́ rẹ;Wọ́n á máa sọ nípa iṣẹ́ ńlá rẹ.+
5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+
98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+
8 Kí àwọn èèyàn máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà+ nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀Àti nítorí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀ lórí àwọn ọmọ èèyàn.+