2 Tímótì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Síbẹ̀, ìpìlẹ̀ Ọlọ́run lágbára, ó dúró digbí, ó ní èdìdì yìí, “Jèhófà* mọ àwọn tó jẹ́ tirẹ̀,”+ àti pé, “Kí gbogbo àwọn tó ń pe orúkọ Jèhófà*+ kọ àìṣòdodo sílẹ̀ pátápátá.”
19 Síbẹ̀, ìpìlẹ̀ Ọlọ́run lágbára, ó dúró digbí, ó ní èdìdì yìí, “Jèhófà* mọ àwọn tó jẹ́ tirẹ̀,”+ àti pé, “Kí gbogbo àwọn tó ń pe orúkọ Jèhófà*+ kọ àìṣòdodo sílẹ̀ pátápátá.”