31 Ọ̀gbọ̀ àti ọkà bálì ti run, torí pé ọkà bálì wà nínú ṣírí, ọ̀gbọ̀ sì ti yọ òdòdó. 32 Àmọ́ kò sóhun tó ṣe àlìkámà* àti ọkà sípẹ́ẹ̀tì torí wọ́n máa ń pẹ́ so.*
9 “Kí o sì mú àlìkámà,* ọkà bálì, ẹ̀wà pàkálà, ẹ̀wà lẹ́ńtìlì, jéró àti ọkà sípẹ́ẹ̀tì, kí o kó wọn sínú ìkòkò kan, kí o sì fi wọ́n ṣe búrẹ́dì tí wàá jẹ. Iye ọjọ́ tí o fi ẹ̀gbẹ́ rẹ dùbúlẹ̀ ni wàá fi jẹ ẹ́, ìyẹn irínwó dín mẹ́wàá (390) ọjọ́.+