Àìsáyà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà sọ fún mi pé: “Mú wàláà+ ńlá kan, kí o sì fi kálàmù lásán,* kọ ‘Maheri-ṣalali-háṣí-básì’* sára rẹ̀. Jeremáyà 36:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mú àkájọ ìwé kan, kí o sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo bá ọ sọ sínú rẹ̀, ọ̀rọ̀ tí mo sọ sí Ísírẹ́lì àti Júdà+ àti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè,+ láti ọjọ́ tí mo kọ́kọ́ bá ọ sọ̀rọ̀ nígbà ayé Jòsáyà, títí di òní yìí.+
8 Jèhófà sọ fún mi pé: “Mú wàláà+ ńlá kan, kí o sì fi kálàmù lásán,* kọ ‘Maheri-ṣalali-háṣí-básì’* sára rẹ̀.
2 “Mú àkájọ ìwé kan, kí o sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo bá ọ sọ sínú rẹ̀, ọ̀rọ̀ tí mo sọ sí Ísírẹ́lì àti Júdà+ àti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè,+ láti ọjọ́ tí mo kọ́kọ́ bá ọ sọ̀rọ̀ nígbà ayé Jòsáyà, títí di òní yìí.+