Sáàmù 25:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni rere àti adúróṣinṣin ni Jèhófà.+ Ìdí nìyẹn tó fi ń kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà tó yẹ kí wọ́n tọ̀.+ י [Yódì] 9 Yóò darí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ láti ṣe ohun tí ó tọ́,*+Yóò sì kọ́ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ní ọ̀nà rẹ̀.+
8 Ẹni rere àti adúróṣinṣin ni Jèhófà.+ Ìdí nìyẹn tó fi ń kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà tó yẹ kí wọ́n tọ̀.+ י [Yódì] 9 Yóò darí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ láti ṣe ohun tí ó tọ́,*+Yóò sì kọ́ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ní ọ̀nà rẹ̀.+