Hósíà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Éfúrémù á sọ pé, ‘Kí ni mo tún fẹ́ wá lọ sọ́dọ̀ àwọn òrìṣà?’+ Màá dáhùn, màá sì máa ṣọ́ ọ.+ Màá dà bí igi júnípà tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀. Wàá sì máa rí èso lọ́dọ̀ mi.” Sekaráyà 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò pa orúkọ àwọn òrìṣà rẹ́ ní ilẹ̀ náà,+ wọn ò sì ní rántí wọn mọ́; èmi yóò sì mú àwọn wòlíì+ àti ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.
8 Éfúrémù á sọ pé, ‘Kí ni mo tún fẹ́ wá lọ sọ́dọ̀ àwọn òrìṣà?’+ Màá dáhùn, màá sì máa ṣọ́ ọ.+ Màá dà bí igi júnípà tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀. Wàá sì máa rí èso lọ́dọ̀ mi.”
2 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò pa orúkọ àwọn òrìṣà rẹ́ ní ilẹ̀ náà,+ wọn ò sì ní rántí wọn mọ́; èmi yóò sì mú àwọn wòlíì+ àti ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.