24 Torí náà, ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ẹ̀yin èèyàn mi tó ń gbé ní Síónì, ẹ má bẹ̀rù nítorí ará Ásíríà tó ti máa ń fi ọ̀pá lù yín,+ tó sì máa ń gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè sí yín bíi ti Íjíbítì.+
26 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa yọ pàṣán kan sí i,+ bó ṣe ṣe nígbà tó ṣẹ́gun Mídíánì lẹ́gbẹ̀ẹ́ àpáta Órébù.+ Ọ̀pá rẹ̀ máa wà lórí òkun, ó sì máa nà á sókè bó ṣe ṣe sí Íjíbítì.+