-
Jeremáyà 5:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Nítorí àwọn èèyàn burúkú wà láàárín àwọn èèyàn mi.
Wọ́n ń wò bí àwọn pẹyẹpẹyẹ tó lúgọ.
Wọ́n ń dẹ pańpẹ́ ikú.
Èèyàn ni wọ́n ń mú.
-