2 Kíróníkà 32:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Hẹsikáyà wá ní ọrọ̀ tó pọ̀ gan-an àti ògo;+ ó ṣe àwọn ilé ìkẹ́rùsí+ fún ara rẹ̀ láti máa kó fàdákà sí àti wúrà pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye, òróró básámù, àwọn apata àti gbogbo àwọn ohun èlò tó ṣeyebíye.
27 Hẹsikáyà wá ní ọrọ̀ tó pọ̀ gan-an àti ògo;+ ó ṣe àwọn ilé ìkẹ́rùsí+ fún ara rẹ̀ láti máa kó fàdákà sí àti wúrà pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye, òróró básámù, àwọn apata àti gbogbo àwọn ohun èlò tó ṣeyebíye.