Àìsáyà 62:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+ Ìfihàn 22:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “‘Wò ó! Mò ń bọ̀ kíákíá, èrè tí mo sì ń fúnni wà pẹ̀lú mi, láti san ẹ̀san fún kálukú bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ bá ṣe rí.+
11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+
12 “‘Wò ó! Mò ń bọ̀ kíákíá, èrè tí mo sì ń fúnni wà pẹ̀lú mi, láti san ẹ̀san fún kálukú bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ bá ṣe rí.+