7 “Rántí, má sì gbàgbé bí o ṣe múnú bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ní aginjù.+ Láti ọjọ́ tí ẹ ti kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì títí ẹ fi dé ibí yìí lẹ ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà.+
9 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń ṣe àwọn nǹkan tí Jèhófà Ọlọ́run wọn sọ pé kò tọ́. Wọ́n ń kọ́ àwọn ibi gíga ní gbogbo àwọn ìlú wọn,+ láti ilé ìṣọ́ títí dé ìlú olódi.*