Míkà 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wọ́n á lá erùpẹ̀ bí ejò;+Wọ́n á máa gbọ̀n rìrì bí wọ́n ṣe ń jáde látinú ibi ààbò wọn bí àwọn ẹran tó ń fàyà fà. Wọ́n á wá sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wa pẹ̀lú ìbẹ̀rù,Ẹ̀rù rẹ yóò sì bà wọ́n.”+
17 Wọ́n á lá erùpẹ̀ bí ejò;+Wọ́n á máa gbọ̀n rìrì bí wọ́n ṣe ń jáde látinú ibi ààbò wọn bí àwọn ẹran tó ń fàyà fà. Wọ́n á wá sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wa pẹ̀lú ìbẹ̀rù,Ẹ̀rù rẹ yóò sì bà wọ́n.”+