-
Jeremáyà 39:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “Lọ sọ fún Ebedi-mélékì+ ará Etiópíà pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Wò ó, màá mú ọ̀rọ̀ tí mo sọ sórí ìlú yìí ṣẹ, pé àjálù ni màá mú bá a, kì í ṣe ire, á ṣojú rẹ lọ́jọ́ tó bá ṣẹlẹ̀.”’
-