-
Jeremáyà 41:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nígbà tí Jóhánánì+ ọmọ Káréà àti gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun tó wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ gbogbo ohun búburú tí Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà ti ṣe,
-
-
Jeremáyà 41:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Jóhánánì ọmọ Káréà àti gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun tó wà pẹ̀lú rẹ̀ kó àwọn èèyàn tó ṣẹ́ kù ní Mísípà, ìyẹn àwọn tó gbà sílẹ̀ lọ́wọ́ Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà, lẹ́yìn tó ti pa Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù. Wọ́n kó àwọn ọkùnrin, àwọn ọmọ ogun, àwọn obìnrin, àwọn ọmọdé àti àwọn òṣìṣẹ́ ààfin pa dà dé láti Gíbíónì.
-
-
Jeremáyà 43:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Asaráyà ọmọ Hóṣáyà àti Jóhánánì+ ọmọ Káréà pẹ̀lú gbogbo àwọn ọkùnrin tó jẹ́ agbéraga wá sọ fún Jeremáyà pé: “Irọ́ lò ń pa! Jèhófà Ọlọ́run wa kò rán ọ kí o sọ pé, ‘Ẹ má lọ sí Íjíbítì láti máa gbé ibẹ̀.’
-