Jeremáyà 39:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+
10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+