Jeremáyà 10:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wọ́n ti sọ àgọ́ mi di ahoro, wọ́n sì ti fa gbogbo okùn àgọ́ mi já.+ Àwọn ọmọkùnrin mi ti fi mí sílẹ̀, wọn kò sì sí mọ́.+ Kò sí ẹni tó ṣẹ́ kù tó máa gbé àgọ́ mi ró tàbí tó máa ta aṣọ àgọ́ mi.
20 Wọ́n ti sọ àgọ́ mi di ahoro, wọ́n sì ti fa gbogbo okùn àgọ́ mi já.+ Àwọn ọmọkùnrin mi ti fi mí sílẹ̀, wọn kò sì sí mọ́.+ Kò sí ẹni tó ṣẹ́ kù tó máa gbé àgọ́ mi ró tàbí tó máa ta aṣọ àgọ́ mi.