Émọ́sì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta àwọn ọmọ Ámónì+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n la inú àwọn aboyún Gílíádì kí wọ́n lè mú agbègbè tiwọn fẹ̀ sí i.+
13 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta àwọn ọmọ Ámónì+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n la inú àwọn aboyún Gílíádì kí wọ́n lè mú agbègbè tiwọn fẹ̀ sí i.+