Ọbadáyà 1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ìran tí Ọbadáyà* rí: Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nípa Édómù nìyí:+ “A ti gbọ́ ìròyìn kan látọ̀dọ̀ Jèhófà,Aṣojú kan ti lọ jíṣẹ́ fún àwọn orílẹ̀-èdè pé: ‘Ẹ dìde, ẹ jẹ́ ká múra láti bá a jagun.’”+
1 Ìran tí Ọbadáyà* rí: Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nípa Édómù nìyí:+ “A ti gbọ́ ìròyìn kan látọ̀dọ̀ Jèhófà,Aṣojú kan ti lọ jíṣẹ́ fún àwọn orílẹ̀-èdè pé: ‘Ẹ dìde, ẹ jẹ́ ká múra láti bá a jagun.’”+