Àìsáyà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Damásíkù:+ “Wò ó! Damásíkù ò ní jẹ́ ìlú mọ́,Ó sì máa di àwókù.+ Émọ́sì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+
3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+