Ìfihàn 17:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìwo mẹ́wàá+ tí o rí àti ẹranko náà,+ máa kórìíra aṣẹ́wó náà,+ wọ́n máa sọ ọ́ di ahoro, wọ́n á tú u sí ìhòòhò, wọ́n máa jẹ ẹran ara rẹ̀, wọ́n sì máa fi iná sun ún pátápátá.+
16 Ìwo mẹ́wàá+ tí o rí àti ẹranko náà,+ máa kórìíra aṣẹ́wó náà,+ wọ́n máa sọ ọ́ di ahoro, wọ́n á tú u sí ìhòòhò, wọ́n máa jẹ ẹran ara rẹ̀, wọ́n sì máa fi iná sun ún pátápátá.+