Àìsáyà 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Bí egbin tí wọ́n ń dọdẹ àti bí agbo ẹran tí kò sí ẹnikẹ́ni tó máa kó wọn jọ,Kálukú máa pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀;Kálukú sì máa sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+ Jeremáyà 51:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “A gbìyànjú láti mú Bábílónì lára dá, ṣùgbọ́n ara rẹ̀ kò yá. Ẹ fi í sílẹ̀, kí kálukú máa lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+ Nítorí ìdájọ́ rẹ̀ ti dé ọ̀run;Ó ti ga sókè bíi sánmà.+
14 Bí egbin tí wọ́n ń dọdẹ àti bí agbo ẹran tí kò sí ẹnikẹ́ni tó máa kó wọn jọ,Kálukú máa pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀;Kálukú sì máa sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+
9 “A gbìyànjú láti mú Bábílónì lára dá, ṣùgbọ́n ara rẹ̀ kò yá. Ẹ fi í sílẹ̀, kí kálukú máa lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+ Nítorí ìdájọ́ rẹ̀ ti dé ọ̀run;Ó ti ga sókè bíi sánmà.+