Jeremáyà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ni mo bá sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! O ti tan àwọn èèyàn yìí+ àti Jerúsálẹ́mù jẹ pátápátá, o sọ pé, ‘Ẹ máa ní àlàáfíà,’+ nígbà tó jẹ́ pé idà ló wà lọ́rùn wa.”* Jeremáyà 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ṣé o kọ Júdà sílẹ̀ pátápátá ni, àbí o* ti kórìíra Síónì dé góńgó ni?+ Kí nìdí tí o fi lù wá débi tí a ò fi lè rí ìwòsàn?+ À ń retí àlàáfíà, àmọ́ ohun rere kan ò dé,À ń retí àkókò ìwòsàn, àmọ́ ìpayà là ń rí!+
10 Ni mo bá sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! O ti tan àwọn èèyàn yìí+ àti Jerúsálẹ́mù jẹ pátápátá, o sọ pé, ‘Ẹ máa ní àlàáfíà,’+ nígbà tó jẹ́ pé idà ló wà lọ́rùn wa.”*
19 Ṣé o kọ Júdà sílẹ̀ pátápátá ni, àbí o* ti kórìíra Síónì dé góńgó ni?+ Kí nìdí tí o fi lù wá débi tí a ò fi lè rí ìwòsàn?+ À ń retí àlàáfíà, àmọ́ ohun rere kan ò dé,À ń retí àkókò ìwòsàn, àmọ́ ìpayà là ń rí!+