Àìsáyà 29:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àmọ́ màá mú ìdààmú bá Áríélì,+Ó máa ṣọ̀fọ̀, ó máa dárò,+Ó sì máa dà bí ibi ìdáná pẹpẹ Ọlọ́run fún mi.+ Jeremáyà 7:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Fá irun gígùn* rẹ, kí o dà á nù, kí o sì kọ orin arò* lórí àwọn òkè, nítorí pé Jèhófà ti kọ ìran àwọn èèyàn tó mú un bínú yìí, yóò sì pa á tì.
2 Àmọ́ màá mú ìdààmú bá Áríélì,+Ó máa ṣọ̀fọ̀, ó máa dárò,+Ó sì máa dà bí ibi ìdáná pẹpẹ Ọlọ́run fún mi.+
29 “Fá irun gígùn* rẹ, kí o dà á nù, kí o sì kọ orin arò* lórí àwọn òkè, nítorí pé Jèhófà ti kọ ìran àwọn èèyàn tó mú un bínú yìí, yóò sì pa á tì.