Ẹ́kísódù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+ Diutarónómì 26:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà sì ti gbọ́ ohun tí o kéde lónìí pé o máa di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,*+ bó ṣe ṣèlérí fún ọ gẹ́lẹ́ àti pé o máa pa gbogbo àṣẹ rẹ̀ mọ́, Sáàmù 135:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jáà ti yan Jékọ́bù fún ara rẹ̀,Ó ti yan Ísírẹ́lì ṣe ohun ìní rẹ̀ pàtàkì.*+
5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+
18 Jèhófà sì ti gbọ́ ohun tí o kéde lónìí pé o máa di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,*+ bó ṣe ṣèlérí fún ọ gẹ́lẹ́ àti pé o máa pa gbogbo àṣẹ rẹ̀ mọ́,